-
Jóòbù 19:13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
13 Ó ti lé àwọn arákùnrin mi jìnnà réré sí mi,
Àwọn tó sì mọ̀ mí ti kúrò lọ́dọ̀ mi.+
-
-
Jòhánù 1:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ó wá sí ilé òun fúnra rẹ̀, àmọ́ àwọn èèyàn rẹ̀ ò gbà á.
-