Róòmù 15:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí Kristi pàápàá kò ṣe ohun tó wù ú,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹ̀gàn ẹnu àwọn tó ń pẹ̀gàn rẹ sì ti wá sórí mi.”+
3 Nítorí Kristi pàápàá kò ṣe ohun tó wù ú,+ bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ẹ̀gàn ẹnu àwọn tó ń pẹ̀gàn rẹ sì ti wá sórí mi.”+