Àìsáyà 49:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+ Hébérù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.
8 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Mo dá ọ lóhùn ní àkókò ojúure,*+Mo sì ràn ọ́ lọ́wọ́ ní ọjọ́ ìgbàlà;+Mò ń ṣọ́ ọ kí n lè fi ọ́ ṣe májẹ̀mú fún àwọn èèyàn náà,+Láti tún ilẹ̀ náà ṣe,Láti mú kí wọ́n gba àwọn ohun ìní wọn tó ti di ahoro,+ Hébérù 5:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.
7 Nígbà tí Kristi wà ní ayé,* ó rawọ́ ẹ̀bẹ̀, ó sì fi ẹkún tó rinlẹ̀ àti omijé tọrọ+ lọ́wọ́ Ẹni tó lè gbà á lọ́wọ́ ikú, a sì gbọ́ ọ, a ṣojúure sí i torí pé ó ní ìbẹ̀rù Ọlọ́run.