Sáàmù 63:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ sàn ju ìyè,+Ètè mi yóò máa yìn ọ́ lógo.+ Sáàmù 109:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àmọ́ ìwọ, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ,Gbèjà mi nítorí orúkọ rẹ.+ Gbà mí sílẹ̀, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára.+
21 Àmọ́ ìwọ, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ,Gbèjà mi nítorí orúkọ rẹ.+ Gbà mí sílẹ̀, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ dára.+