Òwe 14:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ọlọ́gbọ́n máa ń ṣọ́ra, ó sì ń yẹra fún ìwà burúkú,Àmọ́ òmùgọ̀ kì í kíyè sára,* ó sì máa ń dá ara rẹ̀ lójú jù. Oníwàásù 8:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Nítorí pé a kò tètè mú ìdájọ́ ṣẹ lórí ìwà burúkú,+ ọkàn àwọn èèyàn le gbagidi láti ṣe búburú.+
16 Ọlọ́gbọ́n máa ń ṣọ́ra, ó sì ń yẹra fún ìwà burúkú,Àmọ́ òmùgọ̀ kì í kíyè sára,* ó sì máa ń dá ara rẹ̀ lójú jù.