-
Róòmù 11:9, 10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Bákan náà, Dáfídì sọ pé: “Jẹ́ kí tábìlì wọn di ìdẹkùn àti pańpẹ́ àti ohun ìkọ̀sẹ̀ àti ẹ̀san fún wọn. 10 Jẹ́ kí ojú wọn ṣú, kí wọ́n má lè ríran, sì mú kí ẹ̀yìn wọn tẹ̀ ba nígbà gbogbo.”+
-