Ìṣe 1:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé Sáàmù pé, ‘Kí ibi tó ń gbé di ahoro, kí ó má ṣe sí ẹnì kankan tí á máa gbé inú rẹ̀’+ àti pé, ‘Kí ẹlòmíì gba iṣẹ́ àbójútó rẹ̀.’+
20 Nítorí ó wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé Sáàmù pé, ‘Kí ibi tó ń gbé di ahoro, kí ó má ṣe sí ẹnì kankan tí á máa gbé inú rẹ̀’+ àti pé, ‘Kí ẹlòmíì gba iṣẹ́ àbójútó rẹ̀.’+