Sáàmù 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wo ẹni tó lóyún ìwà ìkà;Ọmọ* ìjàngbọ̀n wà nínú rẹ̀, ó sì bí èké.+ Sáàmù 12:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Irọ́ ni wọ́n ń pa fún ara wọn;Wọ́n ń fi ètè wọn pọ́nni,* wọ́n sì ń fi ọkàn ẹ̀tàn* sọ̀rọ̀.+ Sáàmù 55:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ jọ̀lọ̀ ju bọ́tà lọ,+Àmọ́ ìjà ló wà lọ́kàn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tuni lára ju òróró lọ,Àmọ́ idà tí a fà yọ ni wọ́n.+
21 Ọ̀rọ̀ ẹnu rẹ̀ jọ̀lọ̀ ju bọ́tà lọ,+Àmọ́ ìjà ló wà lọ́kàn rẹ̀. Ọ̀rọ̀ rẹ̀ tuni lára ju òróró lọ,Àmọ́ idà tí a fà yọ ni wọ́n.+