2 Sámúẹ́lì 22:2, 3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Ó sọ pé: “Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò+ mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ 3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá. Sáàmù 18:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+ Sáàmù 144:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Òun ni ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ àti ibi ààbò mi,Ibi gíga mi tó láàbò àti olùgbàlà mi,Apata mi àti Ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,+Ẹni tó ń tẹ àwọn èèyàn lórí ba sábẹ́ mi.+
2 Ó sọ pé: “Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò+ mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ 3 Ọlọ́run mi ni àpáta+ mi, ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata+ mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò+ mi,*Àti ibi tí mo lè sá sí,+ olùgbàlà+ mi; ìwọ tí o gbà mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá.
2 Jèhófà ni àpáta gàǹgà mi àti odi ààbò mi àti Ẹni tó ń gbà mí sílẹ̀.+ Ọlọ́run mi ni àpáta mi,+ ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,Apata mi àti ìwo* ìgbàlà mi,* ibi ààbò mi.*+
2 Òun ni ìfẹ́ mi tí kì í yẹ̀ àti ibi ààbò mi,Ibi gíga mi tó láàbò àti olùgbàlà mi,Apata mi àti Ẹni tí mo fi ṣe ibi ààbò,+Ẹni tó ń tẹ àwọn èèyàn lórí ba sábẹ́ mi.+