1 Sámúẹ́lì 17:45 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+ Jeremáyà 17:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ìbùkún ni fún ọkùnrin* tó gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,Ẹni tó fi Jèhófà ṣe ìgbọ́kànlé rẹ̀.+
45 Dáfídì fún Filísínì náà lésì pé: “Ìwọ ń mú idà àti ọ̀kọ̀ àti ẹ̀ṣín*+ bọ̀ wá bá mi jà, ṣùgbọ́n èmi ń bọ̀ wá bá ọ ní orúkọ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ Ọlọ́run ìlà ogun Ísírẹ́lì, ẹni tí o pẹ̀gàn.*+