2 Sámúẹ́lì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Dáfídì kọ ọ̀rọ̀ yìí lórin+ sí Jèhófà ní ọjọ́ tí Jèhófà gbà á lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀+ àti lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.+ 1 Kíróníkà 16:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Lẹ́yìn náà, ó yan lára àwọn ọmọ Léfì láti máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí Jèhófà,+ kí wọ́n máa bọlá fún* Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kí wọ́n máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, kí wọ́n sì máa yìn ín. Sáàmù 9:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Jèhófà, màá fi gbogbo ọkàn mi yìn ọ́;Màá sọ nípa gbogbo iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.+
22 Dáfídì kọ ọ̀rọ̀ yìí lórin+ sí Jèhófà ní ọjọ́ tí Jèhófà gbà á lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọ̀tá rẹ̀+ àti lọ́wọ́ Sọ́ọ̀lù.+
4 Lẹ́yìn náà, ó yan lára àwọn ọmọ Léfì láti máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú Àpótí Jèhófà,+ kí wọ́n máa bọlá fún* Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kí wọ́n máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ̀, kí wọ́n sì máa yìn ín.