Sáàmù 36:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Òdodo rẹ dà bí àwọn òkè ńlá;*+Àwọn ìdájọ́ rẹ dà bí alagbalúgbú ibú omi.+ Àti èèyàn àti ẹranko ni ò ń dá sí,* Jèhófà.+
6 Òdodo rẹ dà bí àwọn òkè ńlá;*+Àwọn ìdájọ́ rẹ dà bí alagbalúgbú ibú omi.+ Àti èèyàn àti ẹranko ni ò ń dá sí,* Jèhófà.+