2 Sámúẹ́lì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Àmọ́, Dáfídì dá Rékábù àti Báánà arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rímónì ará Béérótì lóhùn pé: “Bí Jèhófà ẹni tí ó yọ mí* nínú gbogbo wàhálà+ ti wà láàyè, Sáàmù 103:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó gba ẹ̀mí mi pa dà látinú kòtò,*+Ó sì fi ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ àti àánú dé mi ládé,+
9 Àmọ́, Dáfídì dá Rékábù àti Báánà arákùnrin rẹ̀, àwọn ọmọ Rímónì ará Béérótì lóhùn pé: “Bí Jèhófà ẹni tí ó yọ mí* nínú gbogbo wàhálà+ ti wà láàyè,