Àìsáyà 11:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó máa dá ẹjọ́ àwọn ẹni rírẹlẹ̀ bó ṣe tọ́,*Ó sì máa fi òtítọ́ báni wí torí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ tó wà ní ayé. Ó máa fi ọ̀pá ẹnu rẹ̀ lu ayé,+Ó sì máa fi èémí* ètè rẹ̀ pa ẹni burúkú.+
4 Ó máa dá ẹjọ́ àwọn ẹni rírẹlẹ̀ bó ṣe tọ́,*Ó sì máa fi òtítọ́ báni wí torí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ tó wà ní ayé. Ó máa fi ọ̀pá ẹnu rẹ̀ lu ayé,+Ó sì máa fi èémí* ètè rẹ̀ pa ẹni burúkú.+