1 Àwọn Ọba 4:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Júdà àti Ísírẹ́lì pọ̀ bí iyanrìn etí òkun;+ wọ́n ń jẹ, wọ́n ń mu, wọ́n sì ń yọ̀.+