-
Jóòbù 34:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Èèyàn míì wo ló dà bíi Jóòbù,
Tó ń mu ẹ̀gàn bí ẹni mu omi?
-
-
Jóòbù 34:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Torí o sọ pé, ‘Èèyàn kì í jèrè
Tó bá ń gbìyànjú láti ṣe ohun tí Ọlọ́run fẹ́.’+
-