Nọ́ńbà 15:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 ‘Kí ẹ máa ṣe wajawaja náà síbẹ̀, kí ẹ lè máa rí i, kó sì máa rán yín létí gbogbo àṣẹ Jèhófà, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ọkàn àti ojú yín tó ń mú kí ẹ lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+ Jémíìsì 4:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+
39 ‘Kí ẹ máa ṣe wajawaja náà síbẹ̀, kí ẹ lè máa rí i, kó sì máa rán yín létí gbogbo àṣẹ Jèhófà, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́.+ Ẹ ò gbọ́dọ̀ tẹ̀ lé ọkàn àti ojú yín tó ń mú kí ẹ lọ ṣe àgbèrè ẹ̀sìn.+
4 Ẹ̀yin alágbèrè,* ṣé ẹ ò mọ̀ pé bíbá ayé ṣọ̀rẹ́ ń sọni di ọ̀tá Ọlọ́run ni? Torí náà, ẹnikẹ́ni tó bá fẹ́ jẹ́ ọ̀rẹ́ ayé ń sọ ara rẹ̀ di ọ̀tá Ọlọ́run.+