Diutarónómì 9:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Èèyàn rẹ ni wọ́n, ohun ìní* rẹ+ ni wọ́n sì jẹ́, àwọn tí o fi agbára ńlá rẹ àti apá rẹ tí o nà jáde mú kúrò.’+
29 Èèyàn rẹ ni wọ́n, ohun ìní* rẹ+ ni wọ́n sì jẹ́, àwọn tí o fi agbára ńlá rẹ àti apá rẹ tí o nà jáde mú kúrò.’+