Sáàmù 48:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Gíga rẹ̀ rẹwà, ayọ̀ gbogbo ayé,+Òkè Síónì tó jìnnà réré ní àríwá,Ìlú Ọba Títóbi Lọ́lá.+ Sáàmù 132:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí Jèhófà ti yan Síónì;+Ó fẹ́ kó jẹ́ ibùgbé rẹ̀, ó ní:+