Ìdárò 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà ti pa pẹpẹ rẹ̀ tì;Ó ti ta ibi mímọ́ rẹ̀ nù.+ Ó ti fi ògiri àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò lé ọ̀tá lọ́wọ́.+ Wọ́n ti gbé ohùn wọn sókè ní ilé Jèhófà,+ bíi ti ọjọ́ àjọyọ̀.
7 Jèhófà ti pa pẹpẹ rẹ̀ tì;Ó ti ta ibi mímọ́ rẹ̀ nù.+ Ó ti fi ògiri àwọn ilé gogoro rẹ̀ tó láàbò lé ọ̀tá lọ́wọ́.+ Wọ́n ti gbé ohùn wọn sókè ní ilé Jèhófà,+ bíi ti ọjọ́ àjọyọ̀.