2 Àwọn Ọba 25:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+ Àìsáyà 64:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,Ni wọ́n ti dáná sun,+Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run.
9 Ó dáná sun ilé Jèhófà+ àti ilé* ọba+ pẹ̀lú gbogbo ilé tó wà ní Jerúsálẹ́mù;+ ó tún sun ilé gbogbo àwọn ẹni ńlá.+
11 Ilé* wa mímọ́ àti ológo,*Tí àwọn baba ńlá wa ti yìn ọ́,Ni wọ́n ti dáná sun,+Gbogbo àwọn ohun tó ṣeyebíye sí wa sì ti pa run.