Àìsáyà 48:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Òùngbẹ ò gbẹ wọ́n nígbà tó mú wọn gba àwọn ibi tó ti pa run.+ Ó mú kí omi ṣàn jáde látinú àpáta fún wọn;Ó la àpáta, ó sì mú kí omi rọ́ jáde.”+
21 Òùngbẹ ò gbẹ wọ́n nígbà tó mú wọn gba àwọn ibi tó ti pa run.+ Ó mú kí omi ṣàn jáde látinú àpáta fún wọn;Ó la àpáta, ó sì mú kí omi rọ́ jáde.”+