-
Jẹ́nẹ́sísì 1:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ọlọ́run pe ìmọ́lẹ̀ ní Ọ̀sán, ó sì pe òkùnkùn ní Òru.+ Ilẹ̀ ṣú, ilẹ̀ sì mọ́, èyí ni ọjọ́ kìíní.