-
Sáàmù 89:50, 51Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
50 Jèhófà, rántí ẹ̀gàn tí wọ́n kó bá ìránṣẹ́ rẹ;
Bí mo ṣe fara da ẹ̀gàn gbogbo èèyàn;*
51 Jèhófà, rántí bí àwọn ọ̀tá rẹ ṣé ń sọ̀kò ọ̀rọ̀;
Bí wọ́n ṣe pẹ̀gàn gbogbo ìṣísẹ̀ ẹni àmì òróró rẹ.
-
-
Àìsáyà 52:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “Kí wá ni kí n ṣe níbí?” ni Jèhófà wí.
“Ọ̀fẹ́ ni wọ́n kó àwọn èèyàn mi lọ.
-