1 Sámúẹ́lì 2:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Jèhófà ń sọni di aláìní, ó sì ń sọni di ọlọ́rọ̀;+Ó ń rẹni wálẹ̀, ó sì ń gbéni ga.+ Dáníẹ́lì 2:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+ Dáníẹ́lì 4:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àṣẹ tí àwọn olùṣọ́+ pa nìyí, àwọn ẹni mímọ́ ló sì béèrè fún un, kí àwọn èèyàn tó wà láàyè lè mọ̀ pé Ẹni Gíga Jù Lọ ni Alákòóso nínú ìjọba aráyé,+ ẹni tó bá wù ú ló ń gbé e fún, ẹni tó sì rẹlẹ̀ jù nínú àwọn èèyàn ló ń fi síbẹ̀.” Lúùkù 1:52 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Ó ti rẹ àwọn ọkùnrin alágbára sílẹ̀ látorí ìtẹ́,+ ó sì gbé àwọn tó rẹlẹ̀ ga;+
21 Ó ń yí ìgbà àti àsìkò pa dà,+Ó ń mú ọba kúrò, ó sì ń fi ọba jẹ,+Ó ń fún àwọn ọlọ́gbọ́n ní ọgbọ́n, ó sì ń fún àwọn tó ní òye ní ìmọ̀.+
17 Àṣẹ tí àwọn olùṣọ́+ pa nìyí, àwọn ẹni mímọ́ ló sì béèrè fún un, kí àwọn èèyàn tó wà láàyè lè mọ̀ pé Ẹni Gíga Jù Lọ ni Alákòóso nínú ìjọba aráyé,+ ẹni tó bá wù ú ló ń gbé e fún, ẹni tó sì rẹlẹ̀ jù nínú àwọn èèyàn ló ń fi síbẹ̀.”