Sáàmù 11:5, 6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Jèhófà ń ṣàyẹ̀wò olódodo àti ẹni burúkú;+Ó* kórìíra ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ìwà ipá.+ 6 Yóò dẹ ọ̀pọ̀ pańpẹ́ fún* àwọn ẹni burúkú;Iná, imí ọjọ́+ àti ẹ̀fúùfù gbígbóná ni yóò wà nínú ife wọn.
5 Jèhófà ń ṣàyẹ̀wò olódodo àti ẹni burúkú;+Ó* kórìíra ẹni tó bá nífẹ̀ẹ́ ìwà ipá.+ 6 Yóò dẹ ọ̀pọ̀ pańpẹ́ fún* àwọn ẹni burúkú;Iná, imí ọjọ́+ àti ẹ̀fúùfù gbígbóná ni yóò wà nínú ife wọn.