Náhúmù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Wò ó! Mo dojú ìjà kọ ọ́,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí,+“Màá mú kí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ jóná pátápátá,+Idà yóò sì pa àwọn ọmọ kìnnìún* rẹ run. Mi ò ní jẹ́ kí o mú àwọn èèyàn bí ẹran mọ́ ní ayé,A kò sì ní gbọ́ ohùn àwọn òjíṣẹ́ rẹ mọ́.”+
13 “Wò ó! Mo dojú ìjà kọ ọ́,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí,+“Màá mú kí àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ jóná pátápátá,+Idà yóò sì pa àwọn ọmọ kìnnìún* rẹ run. Mi ò ní jẹ́ kí o mú àwọn èèyàn bí ẹran mọ́ ní ayé,A kò sì ní gbọ́ ohùn àwọn òjíṣẹ́ rẹ mọ́.”+