ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kíróníkà 20:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Ẹ̀rù Ọlọ́run ba gbogbo ìjọba àwọn orílẹ̀-èdè nígbà tí wọ́n gbọ́ pé Jèhófà ti bá àwọn ọ̀tá Ísírẹ́lì jà.+

  • Sáàmù 2:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  4 Ẹni tó wà lórí ìtẹ́ ní ọ̀run á rẹ́rìn-ín;

      Jèhófà máa fi wọ́n ṣẹ̀sín.

       5 Ní àkókò yẹn, á sọ̀rọ̀ sí wọn nínú ìbínú rẹ̀

      Á sì kó jìnnìjìnnì bá wọn nínú ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́