2 Kíróníkà 32:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Ọ̀pọ̀ èèyàn mú ẹ̀bùn wá fún Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì mú àwọn ohun iyebíye wá fún Hẹsikáyà ọba Júdà,+ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè sì ń bọ̀wọ̀ fún un gidigidi lẹ́yìn náà. Sáàmù 89:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Ọlọ́run yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù nínú ìgbìmọ̀* àwọn ẹni mímọ́;+Ó jẹ́ atóbilọ́lá àti ẹni tí ẹ̀rù rẹ̀ ń bani lójú gbogbo àwọn tó yí i ká.+
23 Ọ̀pọ̀ èèyàn mú ẹ̀bùn wá fún Jèhófà ní Jerúsálẹ́mù, wọ́n sì mú àwọn ohun iyebíye wá fún Hẹsikáyà ọba Júdà,+ gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè sì ń bọ̀wọ̀ fún un gidigidi lẹ́yìn náà.
7 Ọlọ́run yẹ lẹ́ni tí à ń bẹ̀rù nínú ìgbìmọ̀* àwọn ẹni mímọ́;+Ó jẹ́ atóbilọ́lá àti ẹni tí ẹ̀rù rẹ̀ ń bani lójú gbogbo àwọn tó yí i ká.+