Sáàmù 34:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Aláìní yìí pe Jèhófà, ó sì gbọ́. Ó gbà á nínú gbogbo wàhálà rẹ̀.+ Òwe 15:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Jèhófà jìnnà réré sí àwọn ẹni burúkú,Àmọ́ ó máa ń gbọ́ àdúrà àwọn olódodo.+