Sáàmù 31:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ní tèmi, jìnnìjìnnì bò mí, mo sì sọ pé: “Màá ṣègbé níwájú rẹ.”+ Àmọ́ nígbà tí mo ké pè ọ́, o gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́.+
22 Ní tèmi, jìnnìjìnnì bò mí, mo sì sọ pé: “Màá ṣègbé níwájú rẹ.”+ Àmọ́ nígbà tí mo ké pè ọ́, o gbọ́ ẹ̀bẹ̀ mi fún ìrànlọ́wọ́.+