-
Sáàmù 9:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 O ti bá àwọn orílẹ̀-èdè wí,+ o sì ti pa àwọn ẹni burúkú run,
O ti nu orúkọ wọn kúrò títí láé àti láéláé.
-
-
Sáàmù 44:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
O fọ́ àwọn orílẹ̀-èdè, o sì lé wọn jáde.+
-