ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 6:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 “Torí náà, sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé: ‘Èmi ni Jèhófà, màá mú yín kúrò lábẹ́ àjàgà àwọn ará Íjíbítì, màá sì gbà yín sílẹ̀ lóko ẹrú.+ Màá fi apá mi tí mo nà jáde* àti àwọn ìdájọ́ tó rinlẹ̀ gbà yín pa dà.+

  • Diutarónómì 9:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Èèyàn rẹ ni wọ́n, ohun ìní* rẹ+ ni wọ́n sì jẹ́, àwọn tí o fi agbára ńlá rẹ àti apá rẹ tí o nà jáde mú kúrò.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́