2 Sámúẹ́lì 22:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Ó ta àwọn ọfà+ rẹ̀, ó sì tú wọn ká;Mànàmáná kọ, ó sì kó wọn sínú ìdàrúdàpọ̀.+ Sáàmù 144:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Mú kí mànàmáná kọ, kí o sì tú àwọn ọ̀tá ká;+Ta àwọn ọfà rẹ, kí o sì mú kí wọ́n wà nínú ìdàrúdàpọ̀.+
6 Mú kí mànàmáná kọ, kí o sì tú àwọn ọ̀tá ká;+Ta àwọn ọfà rẹ, kí o sì mú kí wọ́n wà nínú ìdàrúdàpọ̀.+