-
Àìsáyà 63:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Wọ́n rántí àwọn ìgbà àtijọ́,
Àwọn ọjọ́ Mósè ìránṣẹ́ rẹ̀:
“Ẹni tó mú wọn jáde látinú òkun dà,+ àwọn àti àwọn olùṣọ́ àgùntàn agbo ẹran rẹ̀?+
Ẹni tó fi ẹ̀mí mímọ́ Rẹ̀ sínú rẹ̀ dà,+
-
Ìṣe 7:35, 36Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Mósè yìí kan náà, tí wọ́n sọ pé àwọn ò mọ̀ rí, tí wọ́n sọ fún pé: ‘Ta ló fi ọ́ ṣe alákòóso àti onídàájọ́?’+ òun kan náà ni Ọlọ́run rán+ láti jẹ́ alákòóso àti olùdáǹdè nípasẹ̀ áńgẹ́lì tó fara hàn án látinú igi ẹlẹ́gùn-ún. 36 Ọkùnrin yìí mú wọn jáde,+ ó ṣe àwọn ohun ìyanu* àti iṣẹ́ àmì ní Íjíbítì+ àti ní Òkun Pupa+ àti ní aginjù fún ogójì (40) ọdún.+
-
-
-