Àìsáyà 63:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Màá sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí Jèhófà ṣe torí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ ká yìn,Torí gbogbo ohun tí Jèhófà ti ṣe fún wa,+Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun rere tó ti ṣe fún ilé Ísírẹ́lì,Nínú àánú rẹ̀ àti ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tó lágbára.
7 Màá sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí Jèhófà ṣe torí ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀,Àwọn iṣẹ́ Jèhófà tó yẹ ká yìn,Torí gbogbo ohun tí Jèhófà ti ṣe fún wa,+Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ohun rere tó ti ṣe fún ilé Ísírẹ́lì,Nínú àánú rẹ̀ àti ìfẹ́ rẹ̀ tí kì í yẹ̀ tó lágbára.