-
1 Kíróníkà 29:18, 19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
18 Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá wa, Ábúráhámù, Ísákì àti Ísírẹ́lì, jẹ́ kí àwọn èèyàn rẹ máa ní irú ẹ̀mí àti èrò yìí nínú ọkàn wọn títí láé, kí o sì darí ọkàn wọn sọ́dọ̀ rẹ.+ 19 Kí o fún Sólómọ́nì ọmọ mi ní ọkàn pípé,*+ kí ó lè máa pa àwọn àṣẹ rẹ mọ́+ àti àwọn ìránnilétí rẹ pẹ̀lú àwọn ìlànà rẹ, kí ó lè ṣe gbogbo nǹkan yìí, kí ó sì kọ́ tẹ́ńpìlì* tí mo ti pèsè àwọn nǹkan sílẹ̀ fún.”+
-