Sáàmù 106:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Wọ́n jẹ́ kí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ gbà wọ́n lọ́kàn ní aginjù;+Wọ́n dán Ọlọ́run wò ní aṣálẹ̀.+