-
Ẹ́kísódù 16:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Mósè ń bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ lọ pé: “Nígbà tí Jèhófà bá fún yín ní ẹran jẹ ní alẹ́, tó sì fún yín ní oúnjẹ ní àárọ̀, tí ẹ jẹ àjẹyó, ẹ máa rí i pé Jèhófà ti gbọ́ bí ẹ ṣe ń kùn sí òun. Ta ni àwa jẹ́? Àwa kọ́ lẹ̀ ń kùn sí, Jèhófà ni.”+
-