-
Hébérù 3:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Ìdí nìyẹn tí ọ̀rọ̀ ìran yìí fi kó mi nírìíra, tí mo sì sọ pé: ‘Àwọn èèyàn tó máa ń ṣìnà nínú ọkàn ni wọ́n, wọn ò sì tíì mọ àwọn ọ̀nà mi.’
-