Ẹ́kísódù 16:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 “Mo ti gbọ́ bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ń kùn.+ Sọ fún wọn pé, ‘Ní ìrọ̀lẹ́,* ẹ ó jẹ ẹran, tó bá sì di àárọ̀, ẹ ó jẹ oúnjẹ ní àjẹyó,+ ó sì dájú pé ẹ ó mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”+
12 “Mo ti gbọ́ bí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe ń kùn.+ Sọ fún wọn pé, ‘Ní ìrọ̀lẹ́,* ẹ ó jẹ ẹran, tó bá sì di àárọ̀, ẹ ó jẹ oúnjẹ ní àjẹyó,+ ó sì dájú pé ẹ ó mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run yín.’”+