-
Nọ́ńbà 11:10Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
10 Mósè gbọ́ bí àwọn èèyàn náà ṣe ń sunkún, ní ìdílé kọ̀ọ̀kan, kálukú wà lẹ́nu ọ̀nà àgọ́ rẹ̀. Inú bí Jèhófà gan-an,+ inú Mósè náà ò sì dùn rárá.
-