Nọ́ńbà 14:19, 20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Jọ̀ọ́, ro ti ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tó pọ̀ gan-an, kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn yìí jì wọ́n, bí o ṣe ń dárí jì wọ́n láti Íjíbítì títí di báyìí.”+ 20 Jèhófà wá sọ pé: “Mo dárí jì wọ́n bí o ṣe sọ.+ Jeremáyà 30:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Nítorí mo wà pẹ̀lú rẹ,” ni Jèhófà wí, “láti gbà ọ́. Ṣùgbọ́n màá pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí mo tú ọ ká sí àárín wọn run;+Àmọ́ ní tìrẹ, mi ò ní pa ọ́ run.+ Mi ò ní bá ọ wí* kọjá ààlà,Mi ò sì ní ṣàìfi ìyà jẹ ọ́.”+ Ìdárò 3:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nítorí ìfẹ́ Jèhófà tí kì í yẹ̀ ni ò jẹ́ ká ṣègbé,+Nítorí àánú rẹ̀ kò ní dópin láé.+
19 Jọ̀ọ́, ro ti ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ tó pọ̀ gan-an, kí o sì dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn èèyàn yìí jì wọ́n, bí o ṣe ń dárí jì wọ́n láti Íjíbítì títí di báyìí.”+ 20 Jèhófà wá sọ pé: “Mo dárí jì wọ́n bí o ṣe sọ.+
11 “Nítorí mo wà pẹ̀lú rẹ,” ni Jèhófà wí, “láti gbà ọ́. Ṣùgbọ́n màá pa gbogbo àwọn orílẹ̀-èdè tí mo tú ọ ká sí àárín wọn run;+Àmọ́ ní tìrẹ, mi ò ní pa ọ́ run.+ Mi ò ní bá ọ wí* kọjá ààlà,Mi ò sì ní ṣàìfi ìyà jẹ ọ́.”+