-
Ẹ́kísódù 7:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Sọ fún Áárónì pé, ‘Mú ọ̀pá rẹ, kí o sì na ọwọ́ rẹ sórí omi Íjíbítì,+ sórí àwọn odò rẹ̀, àwọn omi tó ń ṣàn láti ibẹ̀,* àwọn irà rẹ̀+ àti gbogbo adágún omi rẹ̀, kí wọ́n lè di ẹ̀jẹ̀.’ Ẹ̀jẹ̀ yóò wà ní gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì, títí kan inú àwọn ọpọ́n onígi àtèyí tí wọ́n fi òkúta ṣe.”
-