Ẹ́kísódù 8:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jèhófà sì ṣe bẹ́ẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ eṣinṣin mùjẹ̀mùjẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í ya bo ilé Fáráò àti ilé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì.+ Àwọn eṣinṣin náà run ilẹ̀ náà.+
24 Jèhófà sì ṣe bẹ́ẹ̀, ọ̀pọ̀lọpọ̀ eṣinṣin mùjẹ̀mùjẹ̀ bẹ̀rẹ̀ sí í ya bo ilé Fáráò àti ilé àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ àti gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì.+ Àwọn eṣinṣin náà run ilẹ̀ náà.+