Míkà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “Ẹ gbọ́, gbogbo ẹ̀yin èèyàn! Fetí sílẹ̀, ìwọ ayé àti ohun tó wà nínú rẹ,Kí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ jẹ́rìí ta kò yín,+Kí Jèhófà ṣe bẹ́ẹ̀ láti inú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀. Hábákúkù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àmọ́ Jèhófà wà nínú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.+ Gbogbo ayé, ẹ dákẹ́ jẹ́ẹ́ níwájú rẹ̀!’”+
2 “Ẹ gbọ́, gbogbo ẹ̀yin èèyàn! Fetí sílẹ̀, ìwọ ayé àti ohun tó wà nínú rẹ,Kí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ jẹ́rìí ta kò yín,+Kí Jèhófà ṣe bẹ́ẹ̀ láti inú tẹ́ńpìlì mímọ́ rẹ̀.