-
Jeremáyà 44:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Nítorí ẹ ti rú àwọn ẹbọ yìí àti pé ẹ ti ṣẹ̀ sí Jèhófà, tí ẹ kò ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà, tí ẹ kò sì pa òfin àti ìlànà rẹ̀ mọ́ pẹ̀lú àwọn ìránnilétí rẹ̀, ìdí nìyẹn tí àjálù yìí fi bá yín bó ṣe rí lónìí yìí.”+
-