-
Àwọn Onídàájọ́ 3:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Wọ́n ń fi àwọn ọmọbìnrin wọn ṣe aya, wọ́n sì ń fún àwọn ọmọkùnrin wọn ní àwọn ọmọbìnrin tiwọn, wọ́n tún ń sin àwọn ọlọ́run wọn.+
-