Àwọn Onídàájọ́ 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Níkẹyìn, Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì,+ ó sì sọ pé: “Torí pé orílẹ̀-èdè yìí ti da májẹ̀mú mi+ tí mo pa láṣẹ fún àwọn baba ńlá wọn, tí wọn kò sì fetí sí mi,+
20 Níkẹyìn, Jèhófà bínú gidigidi sí Ísírẹ́lì,+ ó sì sọ pé: “Torí pé orílẹ̀-èdè yìí ti da májẹ̀mú mi+ tí mo pa láṣẹ fún àwọn baba ńlá wọn, tí wọn kò sì fetí sí mi,+