9 Nítorí ojú Jèhófà ń lọ káàkiri gbogbo ayé+ láti fi agbára* rẹ̀ hàn nítorí àwọn tí wọ́n ń fi gbogbo ọkàn wọn sìn ín.+ O ti hùwà òmùgọ̀ lórí ọ̀ràn yìí; láti ìsinsìnyí lọ, ogun yóò máa jà ọ́.”+
10 Ta ló pẹ̀gàn ọjọ́ tí nǹkan bẹ̀rẹ̀ wẹ́rẹ́?*+ Inú wọn á dùn, wọ́n á sì rí okùn ìwọ̀n* ní ọwọ́ Serubábélì. Àwọn méje yìí ni ojú Jèhófà, tó ń wò káàkiri ayé.”+